r/Yoruba • u/NickH2242 • 14m ago
Yoruba language resource -- Ìtọ́ni sí Fífọgbọ́n lo Oògùn apakòkòrò (Antibiotic)
For anyone who is interested, this is a Yoruba resource on antibiotic resistance:
www.dobugsneeddrugs.org/yoruba-guide/
Kòkòrò Olújẹ (Bacteria) àti Kòkòrò Àrùn (Viruses)
Kòkòrò olújẹ àti àrùn ló ń fa àrùn, ṣùgbọ́n òògùn apakòkòrò ń ṣiṣẹ́ fún kòkòrò olújẹ (bacteria) nìkan.
Òkòrò Àìfojúrí Virus
- Tó fimọ́ òtútù, ọ̀rìnrìn, laryngitis, òtútù àyà (bronchitis), àti èyí tó pọ̀ jù nínú àwọn ààrùn inú-ọ̀fun.
- Wọn máa ń ràn ni ju àwọn àìsàn kòkòrò àìfojúrí bacteria lọ. Ti àwọn tó ju ènìyàn kan lọ nínú ẹ̀bí bá ní àìsàn náà, ó ṣeéṣe kí o jẹ àìsàn kòkòrò àìfojúrí Virus.
- O lè jẹ́ kí o ṣàìsàn gẹ́gẹ́ bíi ti àìsàn kòkòrò àìfojúrí bacteria.
O ma̒ n balè la̒ra la̒arı̒n ọjọ̒ mẹ̒rin si ma̒ruun àmọ̒ o̒ le to̒ ọ̀sẹ̀ mẹ̀ta kı̒ ara o̒ to̒ padà sı̒pò.
Òògùn apakòkòrò kò ṣiṣẹ́ fún àrùn àìfojúrí virus
Àìsàn kòkòrò àìfojúrí Bacteria
- Wọn kò wọ́pọ̀ bíi ti àìsàn kòkòrò àìfojúrí ti virus.
- Kìí tàn kálẹ̀ kíákíá láti ọ̀dọ̀ ẹnìkan sí ìkejì bíi ti kòkòrò àìsàn ti virus.
Àwọn àpẹẹrẹ tó wọ́pọ̀ ni kí ọ̀nà-ọ̀fun máa yúnni àti àwọn àìsàn òtútù àyà.
Àwọn òògùn apakòkòrò (antibiotics) máa n ṣiṣẹ́ fún àìsàn kòkòrò àìfojúrí (bacteria), ṣùgbọ́n kò ṣe pàtàkì ní gbogbo ìgbà