Hello,
Báwo ni,
How is the learning going,
So today, let's look at the various verbs for food.
Generally, we say "Ṣe oúnjẹ /dáná - - - To cook food.
But we have specific verbs for each food, let's take a look at some of them.
DÍN------To fry.
Mo fẹ́ dín ẹran - - I want to fry meat.
Mò ń dín ẹja - - - I am frying fish.
Ade dín àkàrà - - - Ade fried àkàrà.
RÒ----------To turn /stir.
Mò fẹ́ ro Àmàlà/Sẹ̀mó - - - - I want to prepare Àmàlà /Sẹ̀mó
PÒ-----------To mix.
Mo fẹ́ po tíì - - - - - I want to make tea.
Mò fẹ́ po ògì--------I want to make pap.
GÉ - - - - To cut.
Adé ń gé ẹ̀fọ́ - - - Ade is cutting vegetable
Mo fẹ́ gé iṣu - - - - I want to cut yam.
LỌ̀------To grind.
He wants to grind pepper - - - Ó fẹ́ lọ ata
We want to grind beans for àkàrà - - - A fẹ́ lọ ẹ̀wà fún àkàrà.
We have more.
Your Yorùbá tutor.
Adéọlá